Romu 7:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Dájú, ohun mímọ́ ni Òfin, àwọn àṣẹ tí ó wà ninu rẹ̀ náà sì jẹ́ ohun mímọ́, ohun tí ó tọ́, tí ó sì dára.

Romu 7

Romu 7:6-18