Romu 3:14-17 BIBELI MIMỌ (BM)

14. ẹnu wọn kún fún èpè ati ọ̀rọ̀ burúkú.

15. Ẹsẹ̀ wọn yára láti ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀.

16. Ọ̀nà jamba ati òṣì ni wọ́n ń rìn.

17. Wọn kò mọ ọ̀nà alaafia.

Romu 3