Romu 15:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, nígbà tí mo bá parí ètò yìí, tí mo ti fi ọwọ́ ara mi fún wọn ní ohun tí a rí kójọ, n óo gba ọ̀dọ̀ yín kọjá sí Spania.

Romu 15

Romu 15:27-33