Romu 14:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ jẹ́ kí á máa lépa àwọn nǹkan tí ń mú alaafia wá, ati àwọn nǹkan tí yóo yọrí sí ìdàgbàsókè láàrin ara wa.

Romu 14

Romu 14:9-23