Romu 14:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ fa àwọn tí igbagbọ wọn kò tíì fẹsẹ̀ múlẹ̀ mọ́ra, kì í ṣe láti máa bá wọn jiyàn lórí ohun tí kò tó iyàn.

Romu 14

Romu 14:1-11