Romu 12:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí bí a ti ní ẹ̀yà ara pupọ ninu ara kan, tí gbogbo àwọn ẹ̀yà ara wọnyi kì í sìí ṣe iṣẹ́ kan náà,

Romu 12

Romu 12:1-6