Romu 10:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Kristi ti fi òpin sí Òfin láti mú gbogbo ẹni tí ó bá gbàgbọ́ rí ìdáláre níwájú Ọlọrun.

Romu 10

Romu 10:1-12