Romu 10:20-21 BIBELI MIMỌ (BM)

20. Aisaya pàápàá kò jẹ́ kí ọ̀rọ̀ kọ́ òun lẹ́nu, ó ní,“Àwọn tí kò wá mi ni wọ́n rí mi,àwọn tí kò bèèrè mi ni mo fi ara hàn fún.”

21. Ṣugbọn ohun tí ó ní Ọlọrun wí fún Israẹli ni pé, “Láti òwúrọ̀ títí di alẹ́ ni mo na ọwọ́ mi sí àwọn aláìgbọràn ati alágídí eniyan.”

Romu 10