Romu 10:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wá ń bèèrè, “Ṣé wọn kò ì tíì gbọ́ ni?” Wọ́n kúkú ti gbọ́, nítorí a rí i kà ninu Ìwé Mímọ́ pé,“Ìró wọn ti dé gbogbo orílẹ̀-èdè,àní, ọ̀rọ̀ wọn ti dé òpin ayé.”

Romu 10

Romu 10:14-21