Romu 1:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé ati àwọn Giriki tí wọ́n jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n, ati àwọn kògbédè tí kò mọ nǹkan, gbogbo wọn ni mo jẹ ní gbèsè.

Romu 1

Romu 1:8-19