Peteru Kinni 5:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má ṣe é bí ẹni tí ó fẹ́ jẹ́ aláṣẹ lórí àwọn tí ó wà lábẹ́ yín ṣugbọn ẹ ṣe é bí àpẹẹrẹ fún ìjọ.

Peteru Kinni 5

Peteru Kinni 5:2-9