Peteru Kinni 4:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ẹ bá jìyà gẹ́gẹ́ bí onigbagbọ ẹ má jẹ́ kí ó tì yín lójú, kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa yin Ọlọrun lógo fún orúkọ tí ẹ̀ ń jẹ́.

Peteru Kinni 4

Peteru Kinni 4:7-19