Peteru Kinni 4:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Olukuluku yín ní ẹ̀bùn tirẹ̀. Ẹ máa lo ẹ̀bùn yín fún ire ọmọnikeji yín, gẹ́gẹ́ bí ìríjú oríṣìíríṣìí oore-ọ̀fẹ́ Ọlọrun.

Peteru Kinni 4

Peteru Kinni 4:9-12