Peteru Kinni 3:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní gbolohun kan, ẹ ní inú kan sí ara yín. Ẹ ni ojú àánú. Ẹ ní ìfẹ́ sí ara yín. Ẹ máa ṣoore. Ẹ ní ọkàn ìrẹ̀lẹ̀.

Peteru Kinni 3

Peteru Kinni 3:1-14