Peteru Kinni 2:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wá sọ́dọ̀ ẹni tíí ṣe òkúta ààyè tí eniyan kọ̀ sílẹ̀ ṣugbọn tí Ọlọrun yàn, tí ó ṣe iyebíye lójú rẹ̀.

Peteru Kinni 2

Peteru Kinni 2:1-6