Peteru Kinni 2:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa yẹ́ gbogbo eniyan sí. Ẹ máa fẹ́ràn àwọn onigbagbọ. Ẹ bẹ̀rù Ọlọrun. Ẹ máa bu ọlá fún ọba.

Peteru Kinni 2

Peteru Kinni 2:16-19