Peteru Kinni 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin olùfẹ́ tí ẹ jẹ́ àlejò ní ilẹ̀ àjèjì, mo bẹ̀ yín, ẹ jìnnà sí àwọn ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara tí ó ń bá ọkàn jagun.

Peteru Kinni 2

Peteru Kinni 2:3-14