Peteru Kinni 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ni a ti dáàbò bò nípa agbára Ọlọrun nípa igbagbọ sí ìgbàlà tí a ti ṣe ètò láti fihàn ní ọjọ́ ìkẹyìn.

Peteru Kinni 1

Peteru Kinni 1:1-10