Peteru Kinni 1:3 BIBELI MIMỌ (BM)

A dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun, Baba Jesu Kristi Oluwa wa, tí ó fi ọ̀pọ̀ àánú rẹ̀ tún wa bí sí ìrètí tí ó wà láàyè nípa ajinde Jesu Kristi kúrò ninu òkú.

Peteru Kinni 1

Peteru Kinni 1:1-9