Peteru Kinni 1:24-25 BIBELI MIMỌ (BM)

24. Nítorí,“Gbogbo ẹlẹ́ran-ara dàbí Koríko,gbogbo ògo rẹ̀ dàbí òdòdó.Koríko a máa gbẹ,òdòdó a máa rẹ̀,

25. ṣugbọn ọ̀rọ̀ Oluwa yóo wà títí lae.”Òun ni ọ̀rọ̀ tí à ń waasu rẹ̀ fun yín.

Peteru Kinni 1