Peteru Kinni 1:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí á tó dá ayé ni a ti yan Kristi fún iṣẹ́ yìí. Ṣugbọn ní àkókò ìkẹyìn yìí ni ó tó fi ara hàn nítorí tiyín.

Peteru Kinni 1

Peteru Kinni 1:16-25