Peteru Kinni 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ẹ mọ̀ pé kì í ṣe ohun tí ó lè bàjẹ́, bíi fadaka ati wúrà, ni a fi rà yín pada kúrò ninu ìgbé-ayé asán tí ẹ jogún láti ọ̀dọ̀ àwọn baba yín.

Peteru Kinni 1

Peteru Kinni 1:16-25