Peteru Kinni 1:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó pè yín ti jẹ́ mímọ́, bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ̀yin náà jẹ́ mímọ́ ninu gbogbo ìwà yín.

Peteru Kinni 1

Peteru Kinni 1:5-21