Peteru Kinni 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ ṣe ọkàn yìn gírí. Ẹ máa ṣe pẹ̀lẹ́. Ẹ máa retí oore-ọ̀fẹ́ tí yóo jẹ́ tiyín nígbà tí Jesu Kristi bá tún dé.

Peteru Kinni 1

Peteru Kinni 1:7-17