Peteru Keji 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ó yọ Lọti tí ó jẹ́ olódodo eniyan, tí ọkàn rẹ̀ bàjẹ́ nítorí ìwàkiwà àwọn tí ń ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara wọn.

Peteru Keji 2

Peteru Keji 2:4-11