Peteru Keji 2:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ó sàn fún wọn kí wọn má mọ ọ̀nà òdodo ju pé kí wọn wá mọ̀ ọ́n tán kí wọn wá yipada kúrò ninu òfin mímọ́ tí a ti fi kọ́ wọn.

Peteru Keji 2

Peteru Keji 2:11-22