Peteru Keji 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwa fúnra wa gbọ́ ohùn yìí nígbà tí ó wá láti ọ̀run nítorí a wà pẹlu rẹ̀ lórí òkè mímọ́ nígbà náà.

Peteru Keji 1

Peteru Keji 1:12-21