Orin Solomoni 8:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó bá jẹ pé ògiri ni arabinrin wa,à óo mọ ilé-ìṣọ́ fadaka lé e lórí.Bí ó bá jẹ́ pé ìlẹ̀kùn ni,pákó Kedari ni a óo fi yí i ká.

Orin Solomoni 8

Orin Solomoni 8:7-10