Mo ní n óo gun ọ̀pẹ ọ̀hún,kí n di odi rẹ̀ mú.Kí ọmú rẹ dàbí ìdì èso àjàrà,kí èémí ẹnu rẹ rí bí òórùn èso ápù.