Orin Solomoni 7:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Orí rẹ dàbí adé lára rẹ, ó rí bí òkè Kamẹli,irun rẹ dàbí aṣọ elése-àlùkò tí ó ṣẹ́ léra, wẹ́lẹ́wẹ́lẹ́irun orí rẹ ń dá ọba lọ́rùn.

Orin Solomoni 7

Orin Solomoni 7:1-6