Orin Solomoni 6:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Yíjú kúrò lọ́dọ̀ mi,nítorí wọn kò jẹ́ kí n gbádùn.Irun orí rẹ dàbí ọ̀wọ́ ewúrẹ́ ninu agbo,tí ń sọ̀kalẹ̀ ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè Gileadi.

Orin Solomoni 6

Orin Solomoni 6:1-12