Ẹ̀rẹ̀kẹ́ rẹ̀ dàbí ebè òdòdó olóòórùn dídùn,tí ń tú òórùn dídùn jáde.Ètè rẹ̀ dàbí òdòdó lílì,tí òróró òjíá ń kán níbẹ̀.