Orin Solomoni 4:9 BIBELI MIMỌ (BM)

O ti kó sí mi lẹ́mìí, arabinrin mi, iyawo mi,ẹ̀ẹ̀kan náà tí o ti ṣíjú wò mí,pẹlu nǹkan ọ̀ṣọ́ tí ó wà lọ́rùn rẹ,ni o ti kó sí mi lórí.

Orin Solomoni 4

Orin Solomoni 4:5-10