Orin Solomoni 3:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ló ń jáde bọ̀ láti inú aṣálẹ̀ yìí,tí ó dàbí òpó èéfín,tí ó kún fún òórùn dídùn òjíá ati turari,pẹlu òórùn dídùn àtíkè àwọn oníṣòwò?

Orin Solomoni 3

Orin Solomoni 3:1-9