Orin Solomoni 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fẹ́rẹ̀ má tíì kúrò lọ́dọ̀ wọn,ni mo bá rí ẹni tí ọkàn mi fẹ́.Mo dì í mú, n kò sì jẹ́ kí ó lọ,títí tí mo fi mú un dé ilé ìyá mi,ninu ìyẹ̀wù ẹni tí ó lóyún mi.

Orin Solomoni 3

Orin Solomoni 3:1-8