Orin Solomoni 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo dìde nisinsinyii, n óo sì lọ káàkiri ìlú,n óo wá ẹni tí ọkàn mi fẹ́,ní gbogbo òpópónà ati ní gbogbo gbàgede.Mo wá a ṣugbọn n kò rí i.

Orin Solomoni 3

Orin Solomoni 3:1-9