Olùfẹ́ mi ni ó ni mí, èmi ni mo sì ni olùfẹ́ mi,ó ń da àwọn ẹran rẹ̀, wọn ń jẹko láàrin òdòdó lílì.