Orin Solomoni 2:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Òdòdó Ṣaroni ni mí,ati òdòdó Lílì tí ó wà ninu àfonífojì.

2. Bí òdòdó lílì ti rí láàrin ẹ̀gún,ni olólùfẹ́ mi rí láàrin àwọn ọmọge.

Orin Solomoni 2