Orin Solomoni 1:15-17 BIBELI MIMỌ (BM) Wò ó! O mà dára o, olólùfẹ́ mi;o lẹ́wà pupọ.Ojú rẹ tutù bíi ti àdàbà. Háà, o mà dára o!