Ó ranti ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀, ati òtítọ́ rẹ̀sí àwọn ọmọ Israẹli;gbogbo ayé ti rí ìṣẹ́gun Ọlọrun wa.