Orin Dafidi 96:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ fún OLUWA ní iyì tí ó tọ́ sí orúkọ rẹ̀,ẹ mú ọrẹ lọ́wọ́ wá sinu àgbàlá rẹ̀.

Orin Dafidi 96

Orin Dafidi 96:1-10