Orin Dafidi 96:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kọ orin sí OLUWA, ẹ yin orúkọ rẹ̀;ẹ sọ nípa ìgbàlà rẹ̀ láti ọjọ́ dé ọjọ́.

Orin Dafidi 96

Orin Dafidi 96:1-4