Orin Dafidi 96:12-13 BIBELI MIMỌ (BM)

12. Jẹ́ kí pápá oko ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀ yọ̀.Nígbà náà ni gbogbo igi igbó yóo fi ayọ̀ kọrin,

13. níwájú OLUWA, nítorí pé ó ń bọ̀;ó ń bọ̀ wá ṣe ìdájọ́ ayé.Yóo fi òdodo ṣe ìdájọ́ ayé;yóo sì fi òtítọ́ ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan.

Orin Dafidi 96