Orin Dafidi 94:15 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí pé ìdájọ́ òtítọ́ yóo pada jẹ́ ìpín àwọn olódodo,àwọn olóòótọ́ yóo sì máa tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.

Orin Dafidi 94

Orin Dafidi 94:8-16