Orin Dafidi 94:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé ẹni tí ń jẹ àwọn orílẹ̀-èdè níyà,ni kò ní jẹ yín níyà?Àbí ẹni tí ń fún eniyan ní ìmọ̀, ni kò ní ní ìmọ̀?

Orin Dafidi 94

Orin Dafidi 94:6-20