Orin Dafidi 93:4 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA lágbára lókè!Ó lágbára ju ariwo omi òkun lọ,ó lágbára ju ìgbì omi òkun lọ.

Orin Dafidi 93

Orin Dafidi 93:1-5