Orin Dafidi 92:7 BIBELI MIMỌ (BM)

pé bí eniyan burúkú bá tilẹ̀ rú bíi koríko,tí gbogbo àwọn aṣebi sì ń gbilẹ̀,ó dájú pé ìparun ayérayé ni òpin wọn.

Orin Dafidi 92

Orin Dafidi 92:1-8