Orin Dafidi 92:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ìwọ, OLUWA, ti mú inú mi dùn nípa iṣẹ́ rẹ;OLUWA, mò ń fi ayọ̀ kọrin nítorí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.

Orin Dafidi 92

Orin Dafidi 92:1-7