Orin Dafidi 91:14 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “Nítorí pé ó nífẹ̀ẹ́ sí mi,n óo gbà á là;n óo dáàbò bò ó, nítorí pé ó mọ orúkọ mi.

Orin Dafidi 91

Orin Dafidi 91:9-16