Orin Dafidi 90:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí o tó dá àwọn òkè,ati kí o tó dá ilẹ̀ ati ayé,láti ayérayé, ìwọ ni Ọlọrun.

Orin Dafidi 90

Orin Dafidi 90:1-11